Luke 20:39-40

39 aNígbà náà ni àwọn kan nínú àwọn akọ̀wé dá a lóhùn, pé, “Olùkọ́ ìwọ wí rere!” 40 bWọn kò sì jẹ́ bi í léèrè ọ̀rọ̀ kan mọ́.

Copyright information for YorBMYO